Ọlọ́runtádé

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọlọ́runtádé

God is worth royalty.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlọ́run-tó-adé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlọ́run - god
- is enough, is equal to, is as big as
adé - crown, royalty


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Tádé