Ọlọ́pàádé

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọlọ́pàádé

The Ọpa (re|re) devotee has come.



Àwọn àlàyé mìíràn

Usually written as Ọlọ́pàdé.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

oní-ọ̀pá-dé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

oní - the owner of, the bearer of, the devotee of
ọ̀pá - a deity
dé - arrive, return


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ọlọ́pàdé