Ọlọ́finnúsì
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọlọ́finnúsì
Ọlọ́fin has prestige.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọlọ́fin-ní-ùsì
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọlọ́fin - Ọlọ́fin, a kingly deity as well as the title of many kingsní - to have
ùsì - fame, reputation
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ONDO