Ọlọ́fínlúsì
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọlọ́fínlúsì
Ọlọ́fin has notability.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọlọ́fin-ní-ùsì
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọlọ́fin - Ọlọ́fin, deified ancestral god-king of many towns; king, royal onení - have
ùsì - fame, reputation, renown
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ONDO
EKITI