Ọlọ́fínrótìmí
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọlọ́fínrótìmí
Ọlọ́fin stood with me.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọlọ́fin-ró-tì-mí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọlọ́fin - Ọlọ́fin, deified ancestral god-king of many towns; king, royal oneró - stand (dúró)
tì - with
mí - me
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI