Ọlọ́fínnádé

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọlọ́fínnádé

Ọlọ́fin (of Ìdànrè) owns a crown.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlọ́fin-ní-adé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlọ́fin - Ọlọ́fin, deified ancestral god-king of many towns; king, royal one
- have
adé - crown, royalty


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ọlọ́finládé