Ọlọ́fíndayọ̀mi

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọlọ́fíndayọ̀mi

Ọlọ́fin has become the source of my joy.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlọ́fin-di-ayọ̀-mi



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlọ́fin - Ọlọ́fin, a kingly deity as well as the title of many kings
di - become
ayọ̀ - joy, happiness
mi - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL