Ọlọ́fíndẹ̀rọ̀
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọlọ́fíndẹ̀rọ̀
Ọlọ́fin has become calmness/ease.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọlọ́fin-di-ẹ̀rọ̀
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọlọ́fin - Ọlọ́fin, deified ancestral god-king of many towns; king, royal onedi - become
ẹ̀rọ̀ - ease, softness
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
AKURE