Ọlúgẹmọ

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọlúgẹmọ

One who is skilled at caring for children.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

oní-ù-gẹ̀-ọmọ



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

oní - one who owns
ù - nominalizing prefix
gẹ̀ - to care for; to pamper
ọmọ - child


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI



Irúurú

Onígẹmọ