Ọlọ́nilúà
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọlọ́nilúà
The popular person has a gathering/celebration. [verification needed]
Àwọn àlàyé mìíràn
See Ọlọ́nilúyì, Ọlọ́niètẹ́, Ọlọ́niṣayé
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
oní-ọni-ní-ùà
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
oní - one who owns; hasọni - person (ẹni)
ní - to have
ùà - the society, a gathering, celebration
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI