Ọlọ́finyínká
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọlọ́finyínká
Ọlọ́fin's (presence) surrounds me.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọlọ́fin-yí...ká-n
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọlọ́fin - Ọlọ́fin, deified ancestral god-king of many towns; king, royal oneyí...ká - surround
n - me
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI