Ọlọ́fíntúàbọ̀
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọlọ́fíntúàbọ̀
Ọlọ́fin has brought celebration again.
Àwọn àlàyé mìíràn
See Ọlọ́fíntúàdé
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọlọ́fin-tún-ùà-bọ̀
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọlọ́fin - king, the deified Ọọ̀ni of Ifẹ̀tún - again, afresh, anew
ùà - the society, a gathering, celebration; royal courtyard
bọ̀ - to return, to come
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI