Ọlọ́fíntógùn
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọlọ́fíntógùn
Ọlọ́fin is as powerful as (traditional) medicine.
Àwọn àlàyé mìíràn
More properly written as Ọlọ́fíntóògùn.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọlọ́fin-tó-oògùn
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọlọ́fin - Ọlọ́fin, deified ancestral god-king of many towns; king, royal onetó - suffice for, to be equal to, worthy
oògùn - drugs, medicine, supernatural intervention
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
AKURE