Ọlọ́fínníkà
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọlọ́fínníkà
Ọlọ́fin is not evil.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọlọ́fin-ò-ní-ìkà
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọlọ́fin - Ọlọ́fin, deified ancestral god-king of many towns; king, royal oneò - is not, does not
ní - have
ìkà - a cruel/evil thing
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI