Ọlọ́fínmúyìdé
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọlọ́fínmúyìdé
Olofin has arrived with honor.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọlọ́fin-mú-uyì-dé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọlọ́fin - Ọlọ́fin, deified ancestral god-king of many towns; king, royal onemú - hold onto, pick, bring
uyì - honour, prestige (iyì)
dé - arrive, return
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
AKURE