Ọlọ́fínmúàgún
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọlọ́fínmúàgún
Ọlọ́fin has aligned character; Ọlọ́fin has aligned the society.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọlọ́fin-mú-ùwà-gún, ọlọ́fin-mú-ùà-gún
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọlọ́fin - Ọlọ́fin, deified ancestral god-king of many towns; king, royal onemú - hold (onto)
ùwà - character (ìwà)
gún - set, to align, to be good.
ùà - the society, a gathering, celebration
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI