Ọlọ́fínmẹ́hìntì
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọlọ́fínmẹ́hìntì
Ọlọ́fin supported (me).
Àwọn àlàyé mìíràn
See Ọlọ́fínnẹ́hìntì
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọlọ́fin-mú...tì-ẹ̀hìn
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọlọ́fin - Ọlọ́fin, deified ancestral god-king of many towns; king, royal onemú...tì - to rest on; to support
ẹ̀hìn - back
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ONDO