Ọlọ́fíngbasọ́tẹ̀
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọlọ́fíngbasọ́tẹ̀
Ọlọ́fin did not accept this child in treachery. [verification needed]
Àwọn àlàyé mìíràn
From the town of Ìdànrè, Oǹdó, Nigeria. See Akíngbasọ́tẹ̀, Akíngbésọ́tẹ̀.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọlọ́fin-ò-gba-sí-ọ̀tẹ̀
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọlọ́fin - Ọlọ́fin, deified ancestral god-king of many towns; king, royal oneò - is not, does not
gba - receive, take/take over, accept
sí - into
ọ̀tẹ̀ - treachery, rebellion, betrayal
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ONDO