Ọlọ́fíndùmíyè
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọlọ́fíndùmíyè
Ọlọ́fin struggled for me and I survived.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọlọ́fin-dù-mí-yè
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọlọ́fin - Ọlọ́fin, deified ancestral god-king of many towns; king, royal onedù - struggle
mí - me
yè - survive
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
AKURE