Ọlọ́fíndínà
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọlọ́fíndínà
Ọlọ́fin blocked the way (of evil).
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọlọ́fin-dí-ọ̀nà
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọlọ́fin - Ọlọ́fin, deified ancestral god-king of many towns; king, royal onedí - block
ọ̀nà - road, lane, way, path
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI