Ọlọ́fíndáhùnsi

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọlọ́fíndáhùnsi

Ọlọ́fin has answered my prayers.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlọ́fin-dáhùn-síi



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlọ́fin - Ọlọ́fin, deified ancestral god-king of many towns; king, royal one
dáhùn - answers
síi - to it


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
AKURE



Irúurú

Ọlọ́fíndáhùnsi

Dáhùnsi