Ọlọ́fínṣadé

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọlọ́fínṣadé

Ọlọ́fin has created a crown.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlọ́fin-ṣe-adé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlọ́fin - Ọlọ́fin, deified ancestral god-king of many towns; king, royal one
ṣe - make, create (something good)
adé - crown, royalty


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI



Irúurú

Ṣadé