Ọlọ́fínṣùsì
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọlọ́fínṣùsì
Ọlọ́fin has created notability.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọlọ́fin-ṣe-ùsì
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọlọ́fin - Ọlọ́fin, deified ancestral god-king of many towns; king, royal oneṣe - make
ùsì - reputation, prominence
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI