Ọláwámirí

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọláwámirí

Honor has found me at last.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlá-wá-mi-rí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlá - honour, nobility, wealth, success, prestige
- come, arrive
mi - me
- see


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Láwámirí

Wámirí