Ọlámikúnlé
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọlámikúnlé
My honor fills the home.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọlá-mi-kún-ilé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọlá - honour, prestige, wealth, nobilitymi - mine
kún - in addition to, fulfillment
ilé - house
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL