Ọlámídòtun

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọlámídòtun

My success/wealth is renewed.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlá-mi-di-ọ̀tun



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọ̀lá - wealth, nobility, notability, success
mi - mine
di - become
ọ̀tun - renewed, new


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL
IFE



Irúurú

Dọ̀tun

Ọládọ̀tun