Ọlájàre

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọlájàre

Honor is justified.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlá-jàre



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlá - honour, wealth, success, notability
jàre - be justified


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Jàre