Ọlágùndóyè

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọlágùndóyè

Honor has spread/extended and reached a chieftaincy title.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlá-gùn-dé-oyè



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlá - honour, wealth, success, notability
gùn - climb, mount, to ascend to
- arrive
oyè - chieftaincy title, honor


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO