Ọládékojú
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọládékojú
Honor has come, behold its presence. [verification needed]
Àwọn àlàyé mìíràn
A praise name of the goddess Ọ̀ṣun
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọlá-dé-kò-ojú
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọlá - wealth, prestige, honourdé - arrive, return
kò - to meet
ojú - face
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL