Ọkánlàwọ́n

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọkánlàwọ́n

The only male child among the female children.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọ̀kán-là-wọ́n



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọ̀kan - one
là - split, part
wọ́n - them


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Làwọ́n