Ọdúnladé
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọdúnladé
The crown is festivity/celebration.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọdún-ni-adé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọdún - year, festivityni - is
adé - crown, royalty
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Ọdúnladé Adékọ́lá
Nigerian actor