Ọdúnọlá
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọdúnọlá
HOMOGRAPH Ọdúnọlá: The year of wealth/success. Ọdúnọ́lá: The year has wealth/success.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọdún-ọlá, ọdún-ní-ọlá
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọdún - year, season, festivityní - have
ọlá - wealth, success, nobility
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL