Ọdẹ́tóókí

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọdẹ́tóókí

The hunter is worthy of praise/greeting. The hunter deserves praise/greeting



Àwọn àlàyé mìíràn

Today its simply written as Ọdẹ́tókí, common among the Osun State axis of Yorubaland especially Ilé-Ifẹ̀ and Modákẹ́kẹ́ axis



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọdẹ-tó-kí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọdẹ - hunter
tó - suffice for, worthy of
kí - praise, greet


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ọdẹ́tókí