Ọdẹ́róunbí

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọdẹ́róunbí

The hunter found someone (prominent) to birth.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọdẹ-rí-oun-bí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọdẹ - hunter
- to see, to find
oun - someone, something
- to give birth, to birth


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Róunbí