Sísọ síta
The hunter has entrusted me (with a child).
ọdẹ-jì-mí
Ó pọ̀ ní: ABEOKUTA
Ọdẹ́jìnmí
Jìmí
Bóyá o tiẹ̀ ní ìtàn kan láti sọ fún wa nípa orúkọ yìí, tàbí fún wa ní ǹkan tí a ṣì kọ, tàbí fikún oun kan tí a kọ sílẹ̀.