Ọdẹ́bọ̀dé

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọdẹ́bọ̀dé

The hunter has come; The hunter returns.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọdẹ-bọ̀-dé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọdẹ - hunter
bọ̀ - to return
- arrive, come


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IBADAN



Irúurú

Bọ̀dé