Ọdúnodù

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọdúnodù

The festival of Ifá.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọdún-odù



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọdún - year, festivity
odù - Ifá corpus/text; Ifá divination; message of Ifá


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IJEBU