Ọdẹ́dọlá

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọdẹ́dọlá

Hunting has become honor.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọdẹ-di-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọdẹ - hunter
di - become
ọlá - honour, grace, wealth, success, nobility


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Dọlá