Ọbafúnșó

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọbafúnșó

The king gave me (this child) to look after.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọba-fún-mi-ṣọ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọba - king
fún - give
mi - me
ṣọ́ - care for, cherish, pet


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ILESHA