Ọbátúgà

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọbátúgà

Shortening of Ọbátúgàṣe: the king repaired the throne.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọbá-tún-ùgà-ṣe



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọbá - king
tún - again
ùgà - throne, position, prominence
ṣe - make


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IJEBU



Irúurú

Ọbátúgàṣe

Ọbátúngàṣe