Ọbátúgàṣe

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọbátúgàṣe

The king repaired his throne.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọba-tún...ṣe-ugà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọba - king; Ọbalúayé, the god of disease and healing
tún...ṣe - fixes, repair
ugà - throne (igà)


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL