Ọbálékè

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọbálékè

The king triumphs.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọba-lékè



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọba - king, ruler; Ọbalúayé, the god of disease and healing
lékè - be paramount, be most important, triumph


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OYO



Irúurú

Lékè