Ọbákàmíyẹ

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọbákàmíyẹ

The king (of kings) counts me worthy.



Àwọn àlàyé mìíràn

See: Olúkàmíyẹ



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọba-kà-mí-yẹ



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọba - king
- read, count, consider
- me
yẹ - be respectable, be befitting of


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA
EKO
GENERAL
IJEBU



Irúurú

Kàmíyẹ