Ọbańkẹ́mi

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọbańkẹ́mi

The king cherishes/favours/pampers me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọba-ń-kẹ́-mi



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọba - king, ruler; Ọbalúayé, the god of disease and healing
ń - continue to
kẹ́ - to care for, to cherish
mi - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL