Ọbánọ́yẹ̀n
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọbánọ́yẹ̀n
The king has joy.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọba-ní-ọ̀yẹ̀n
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọba - king, ruler; Ọbalúayé, the god of disease and healingní - have, own; in
ọ̀yẹ̀n - joy, excitement (ọ̀yìn)
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OWO