Ọṣìnkálú

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọṣìnkálú

The Ọṣìn deity is famous around the town.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọṣìn-ká-ìlú



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọṣìn - king, first one, Ọṣìn deity
- all around (káàkiri)
ìlú - town


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IJEBU



Irúurú

Ọshìnkálú

Ọṣìkálú

Ọshìkálú