Ọ̀wọ́lẹ́wà

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọ̀wọ́lẹ́wà

Honour/Respect is beautiful.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọwọ̀-ní-ẹwà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọwọ̀ - honour, regard, respect
ní - have
ẹwà - beauty


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IGBOMINA