Ọ̀wọ́adé
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọ̀wọ́adé
A procession of royalty.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọ̀wọ́-adé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọ̀wọ́ - a group of people, a herdadé - crown, royalty
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Abímbọ́lá Akeem Ọ̀wọ́adé: the Aláàfin of Ọ̀yọ́ (elect) 2025