Ọ̀sanyíntúkẹ́
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọ̀sanyíntúkẹ́
Ọ̀sanyìn has provided care again.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọ̀sanyìn-tún-kẹ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọ̀sanyìn - The Yorùbá deity of herbs and medicinetún - again
kẹ́ - to take care of, to pamper
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
AKURE