Ọ̀pádèrè

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọ̀pádèrè

Òrìṣàoko has become an idol/figurine (to be worshipped).



Àwọn àlàyé mìíràn

The ọ̀pá is a root common to names of worshippers of the Òrìṣà oko, the deity of fertility and harvest. Read more here: http://www.ifafoundation.org/orisha-oko



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọ̀pá-dì-erè



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọ̀pá - staff; a symbol of the deity Òrìṣàoko
- become
erè - idol, statue, figurine


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IBADAN



Irúurú

Dèrè